Song: Ayé Le
Artist:  PELUMIKISS
Year: 2021
Viewed: 34 - Published at: 7 years ago

Intro:
Oh nananana
Kiss
Pelumi on this one

Verse:
To become a man
Isn’t a days job
Oluwa lo n bukun fun ni
Lai se laalaa ah
Baba bukun fun mi
Ke mi maa tawona
Baba bukun fun mi
Ke mi maa se taraka

Bridge:
Ibi ti egbe mi ti n na owo
Ke mi maa se na oju ni be oh
Ibi egbe mi ti n soro
Baba maa je n gbenu daake X2
Chorus:
Aah aye le
Aye yii maa le (Ayé àkámarà)
Aaah aye le
Aye yii maa le (Ayé tó ń yaa ni láì lo camera) x2

Hook:
Na why I dey pray for blessings
Blessings from above
Ojo ibukun re
Ko ro lemi lori


Chorus:
Aah aye le
Aye yii maa le (Ayé àkámarà)
Aaah aye le
Aye yii maa le (Ayé tó ń yaa ni láì lo camera) x2

( PELUMIKISS )
www.ChordsAZ.com

TAGS :