Song: OBA NI
Artist:  P. SAM
Year: 2020
Viewed: 3 - Published at: a year ago

(Chorus)
Eba mi pe o
OBA ni
OBA ni
OBA ni
OBA nla lo je o
OBA ni
Pe e OBA

Ani eba mi pe o
OBA ni
OBA ni
OBA ni
OBA nla lo je o
OBA ni
Pe e OBA

(Verse 1)
Ogbeni nija keru bonija
Olorun nla sha ni o
Iwo L'Olorun ti mo mo
To n gbeja eni
Iwo L'Olorun ti mo mo
To n toju eni nigbagbo
Ijinle Ife atofarati o bi oke
Oke nla ti n kamo laya jinjin
Yagboyaju okunrin ogun
Awuwo masegbe
Ijinle Ife atofarati bi oke
Iwo sha L'Olorun ti mo mo nigbagbo

(Chorus)

Eba mi pe o
OBA ni
OBA ni
OBA ni
OBA nla lo je o
OBA ni
Pe e OBA

Ani eba mi pe o
OBA ni ( e pe e)
OBA ni
OBA ni
OBA nla lo je o
OBA ni
Pe e OBA

(Verse 2)
I have searched through all thе Earth
I have found no one like you
Nigbagbo agbaiyе kosi o
OBA le o ma je in all circumstances
Mo woke
Mo wole
Mo wotun
Mo wosi eh
Eyin ni mo ba n be o

If I say make I count your mercy
For my life o o o
I go lose count o
Anu re lori mi o
Ko se fenuso oh oh oh

(Chorus)
OBA ni
OBA ni
OBA ni
OBA nla lo je o
OBA ni
Pe e OBA

Eba mi pe o
OBA ni
OBA ni
OBA ni
OBA nla lo je o
OBA ni
Pe e OBA
(HOOK)
Pe e
OBA
OBA OBA ah

Epe e OBA
OBA nla lo je o
OBA ni

Ani epe e
OBA
OBA OBA ah

Epe e OBA
OBA nla lo je o
OBA ni

(Chorus)
Eba mi pe o OBA ni
OBA ni
OBA ni
OBA nla lo je o
OBA ni
Pe e OBA


OBA ni
OBA ni
OBA ni
OBA nla lo je o
OBA ni
Pe e OBA

( P. SAM )
www.ChordsAZ.com

TAGS :