Song: Olumo
Artist:  Brymo
Year: 2018
Viewed: 39 - Published at: 10 years ago

Mò n lọ sáké mo fẹ́ lọ rọ́jọ̀gbọ́n o
Mò n lọ sábéòkúta mo fé lọ rí
Ọmọ ṣóyínká
Oṣóyinká ooooo
Oṣóyinká
Oṣóyinká ooooo

Bẹ lọ sówu
Bẹ bá rárẹ̀mú o
Bẹ bá rí bába Ìyábọ̀, ẹ bá mi ki
Ẹbọra òwu
Ẹbọra òwu ooooo
Ẹbọra òwu, eh
Ẹbọra òwu ooooo

Bẹ lọ sábẹ́òkúta ìlú olúmọ
Bẹ bá ráláké ẹ bá mi ki

( Brymo )
www.ChordsAZ.com

TAGS :