Song: Mo Fiyin Fun
Artist:  Timi Osukoya
Year: 2021
Viewed: 179 - Published at: 6 years ago

Mo fiyin fun
Oba to mo ibere mi
Mo fiyin fun
Oba to mo ibere mi
Alpha Omega
Oba to pe ye o
Ologo ato olola
Mo fiyin fun

Mo fiyin fun
Oba to mo ibere mi
Mo fiyin fun
Oba to mo ibere mi
Alpha Omega
Oba to pe ye o
Ologo ato olola
Mo fiyin fun

Mo fiyin fun
Oba to mo ibere mi
Mo fiyin fun
Oba to mo ibere mi
Alpha Omega
Oba to pe ye o
Ologo ato olola
Mo fiyin fun
B’o ba ni Jesu k’o dimu
K’o si toro imuduro
Jesu, Oluwa mi
Mu mi duro dopin

Mu mi duro, mu mi duro
Mu mi duro dopin
Jesu, Oluwa mi
Mu mi duro dopin

Nigbat’ o ku emi nikan
Ti ko si alabaro mo
Jesu, Oluwa mi,
Mu mi duro dopin

Mu mi duro, mu mi duro
Mu mi duro dopin
Jesu, Oluwa mi
Mu mi duro dopin

Jesu, Oluwa mi
Mu mi duro dopin
Jesu, Oluwa mi
Mu mi duro dopin

Mu mi duro dopin
Mu mi duro dopin

( Timi Osukoya )
www.ChordsAZ.com

TAGS :